Tumgik
edeyorubarewa · 3 years
Photo
Tumblr media
Àwọn Yorùbá bọ̀, Wọ́n ní òwe lesin ọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀ lesin òwe, tí ọ̀rọ̀ bá sọnù òwe la fi ń wa ṣé lóòótọ́ ni gbólóhùn yìí? Ẹ tẹ́lẹ̀ wá lórí ìkànnì YouTube fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ni ori ìkànnì YouTube 👆👆👆 https://youtu.be/zYYSDdwHD2o https://www.instagram.com/p/CRThQCmpQjn/?utm_medium=tumblr
0 notes
edeyorubarewa · 3 years
Video
Apá kejì Tọkọ-Tayà tí wà lórí ìkànnì YouTube. Ẹ̀ Dákun ẹ bá wa wòó, kí ẹ sì tẹ́lẹ̀ wa lórí ìkànnì YouTube wa, https://youtu.be/3ATWipk11GI Ẹsẹ́ púpọ̀. #TokoTaya #EdeYorubaRewa #YorubaDunLede https://www.instagram.com/p/CQs6BSNIiIP/?utm_medium=tumblr
0 notes
edeyorubarewa · 3 years
Photo
Tumblr media
Apá kejì Tọkọ-Tayà tí wà lórí ìkànnì YouTube. Ẹ̀ Dákun ẹ bá wa ooo, kí ẹ sì tẹ́lẹ̀ wa lórí ìkànnì YouTube wa. Ẹsẹ́ púpọ̀ #TokoTaya #EdeYorubaRewa #YorubaDunLede https://www.instagram.com/p/CQoMO__pMyW/?utm_medium=tumblr
0 notes
edeyorubarewa · 3 years
Photo
Tumblr media
Ẹsẹ́ púpọ̀ fún àtìlẹyìn yín tí ẹ fún wa lórí ìkànnì YouTube lẹ́yìn tí ó jé kí á ní alatele Ọgọ́rùn-ún ólé (over 100 subscribers). Fún ẹ̀yin tí ẹ kò tí tẹ́lẹ̀ wa, ẹ jọ̀wọ́ ẹ bawa tẹ Bọtini tí ẹ ó fi lè tẹ́lẹ̀ wa lórí YouTube 👇👇👇 https://youtube.com/c/EdeYorubaRewa #EdeYorubaRewa #YorubaDunLede #YorubaAbroad https://www.instagram.com/p/CQlSvAlp26v/?utm_medium=tumblr
0 notes
edeyorubarewa · 3 years
Video
Èmi àti ọ̀rẹ́minú mi Emdee Tiamiyu ṣé fọ́nrán yìí tí àkọlé rè ń jẹ Tọkọ-Tayà fún ìgbádùn ẹ̀yin olólùfẹ́ wa. A lérò wípé yíò rán àwọn olólùfẹ́ lọ́wọ́ nipe eré ìfẹ́ wọn, gẹ́gẹ́ bí yíò ṣe ma gbé èdè yorùbá lárugẹ si. A lérò wípé ẹ má je ìgbádùn ẹ. Ẹ Dákun ẹ bá wa fi ránṣé sí àwọn ẹlòmíràn àti kí ẹ tẹ́lẹ̀ wá lórí ẹ̀rọ YouTube e te ate Ilana lati wo fonran naa (Click on bio) https://youtu.be/kjn8kNLrvGw #EdeYorubaRewa #TokoTaya #YorubaCouple (at Birmingham, United Kingdom) https://www.instagram.com/p/CQVRUtNptVG/?utm_medium=tumblr
0 notes
edeyorubarewa · 3 years
Photo
Tumblr media
Ǹjẹ́ ẹ lè so ìtumò àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí?.. #EdeYorubaRewa #YorubaDunLede (at St Giles Church, Sheldon, Church of England) https://www.instagram.com/p/CLElIIIpU7v/?igshid=jm8rknsjvzlg
0 notes
edeyorubarewa · 3 years
Photo
Tumblr media
Amin Ase Edgware #OsuTuntun #OsuErele #EdeYorubaRewa #YorubaDunLede (at Birmingham, United Kingdom) https://www.instagram.com/p/CKvx3TpJGbL/?igshid=1gs7fu4lnupbf
0 notes
edeyorubarewa · 3 years
Video
Se ìwọ sì ń sọ wípé kí àwọn ènìyàn má sọ Yorùbá sí awon ọmọ rẹ mon 🤔🤔🤔🤔. Wo bí wọ́n ṣe ń gbé èdè tí ìwọ ò fẹ́ àwọn ọmọ rẹ sọ ní ìlú aláwò funfun... o je tètè ronú pìwà dà kò má jẹ wípé òyìnbó aláwò funfun ní yíò kò àwọn ọmọ rẹ naa ni èdè abínibí wọn. Mo soyi mọ dúró, ẹni bá létí kò gbò. Ire ooooo #EdeYorubaRewa #YorubaDunLede (at Somewhere in the Universe) https://www.instagram.com/p/CKqYkwGJ6o1/?igshid=1r2w6pb39rgx5
0 notes
edeyorubarewa · 3 years
Video
Òdodo ọ̀rọ̀ rẹ ẹ jẹ́ ká dìjo gbo. Reposted from @sunkanmi_omobolanle https://www.instagram.com/p/CKpRQfbpI3h/?igshid=1k6lmcutgn03o
0 notes
edeyorubarewa · 3 years
Photo
Tumblr media
Kíni orúkọ ti ẹ̀yin ń pe ohun tó wà nínú àwòrán yìí?👇👇👇 Orúkọ márùn-ún ni mo mọn sí. (at Somewhere in the Universe) https://www.instagram.com/p/CKljWJpJ-Rr/?igshid=s52nxoe323h2
0 notes
edeyorubarewa · 3 years
Photo
Tumblr media
Kíni orúkọ ti ẹ̀yin ń pe ohun tó wà nínú àwòrán yìí?👇👇👇 (at Birmingham, United Kingdom) https://www.instagram.com/p/CKjqxdApoSn/?igshid=4rspqwf5cx7x
0 notes
edeyorubarewa · 3 years
Video
Reposted from @adeolafayehun he gave the ultimatum. Igboho said many people have been killed by the herdsmen, including a professor who returned from abroad. He's upset that Yoruba leaders are silent. Also, the Seriki of the Fulani community explained that they were not responsible for the kidnappings. He said it's the work of new Fulani herders from Zamfara & Kebbi, adding that they are also victims. He said he has lived peacefully in Oyo for more than 45 years. https://www.instagram.com/p/CKbSOAbJ2zN/?igshid=9j0gkajkfpm3
0 notes
edeyorubarewa · 3 years
Photo
Tumblr media
Àádọ́ta ọdún lórí ite. Ikú bàbá yèyé, ọmọ Ikú tí Ikú ò gbọdò pa, Ọmọ àrùn tá'rùn ò gbọdò se. Aláàfin Ọ̀yọ́ Oba Lamidi Adeyemi III #AlaafinOyo #ObaOyo #ObaIleYoruba #EdeYorubaRewa (at Birmingham, United Kingdom) https://www.instagram.com/p/CKBJqeBpDMk/?igshid=ff2sogetgedf
0 notes
edeyorubarewa · 3 years
Photo
Tumblr media
Àmín àṣẹ Èdùmàrè #EdeYorubaRewa #OdunTuntun #2021 (at Birmingham, United Kingdom) https://www.instagram.com/p/CJdR9ArpEfc/?igshid=1hcahzgqhym8y
0 notes
edeyorubarewa · 3 years
Photo
Tumblr media
Ayọ̀ abara tíntín 💗💗💗 a n fi asiko yii oba Enitan Ogunwusi Ooni ti ile Ife at Olorì Silekunola ayo ọmọ ọkùnrin làǹtì-lanti ti edumare fi ta won lore. 📸 :Ooni Adimula Ile Ife/ Facebook #EdeYorubaRewa https://www.instagram.com/p/CHulKofpDNh/?igshid=npehysfwalhl
0 notes
edeyorubarewa · 3 years
Photo
Tumblr media
Lẹ́sọ̀ Lẹ́sọ̀ láyé gbà. #EdeYorubaRewa #OroYoruba #OroIsiti https://www.instagram.com/p/CHsD7s8JSfb/?igshid=9facot5yg5nl
0 notes
edeyorubarewa · 3 years
Photo
Tumblr media
Ọ̀rọ̀ kan gbé mi nínú, Tí mo fẹ́ kẹ bámi dá sí, Kí gbogbo mùtúmùwà fetí gbéyàwó ẹ, Ọ̀rọ̀ àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin tó ń bójú Bóra, Ló fa ariwo, Ìyàwó adúláwọ̀, Ọkọ adúláwò Tó fẹ́ para rẹ̀ láwọ̀dà, Bí wọ́n bá bàwó jẹ́ tán, Wọ́n á wá fín pátápátá, Ọsẹ abójú ni wọ́n ń wá kiri, Atíkè abàwọ̀jẹ́ ni wọ́n ń lò lọ́pọ̀ ìgbà, Wọ́n kìí dúró bí Ẹlẹ́dàá ṣe dá wọ́n, Ń ṣe ní wọ́n ń bàwọ̀ jẹ́, Ọ̀pọ̀lọpọ̀ làwọn òbí ò dà mọ̀ mọ́, Nítorí ìgbà t'ọmọ ó kúrò nílé, Ń ṣe ló dúdú bíi kóró isin, Ìpadàbọ́ Odùduwà rèé, Ọmọ tí d'òyìnbó atọwọdá, Ojú lójú "kóòkì" ẹsẹ̀ lẹsẹ̀ "fàntà", Oòrùn ti ń jáde lára wọn kò lẹ́gbẹ́, Ní ìgbẹ̀yìn Ayé abójúbóra, Kii suwòn, Kí ǹkan má ṣe ara wọn ni Búté búté ni ara wọn ó má já, Mo rọ gbogbo ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin adúláwọ̀ kí á wà bí èdùwà ṣe dá wa. Mosọ̀yí, modúrónaa. Mo sì dúpẹ́ Púpọ̀ lọ́wọ́ elédùà tó dá mi sí ilé Adúláwọ̀, #Ìwońkọ #EdeYorubaRewa #YorubaDunLede #EwiYoruba https://www.instagram.com/p/CHImkBgJPy9/?igshid=1g4lqjs0lwxmu
0 notes